Technology

Cryptography

Odù-ìdáàbòbò Noun Odù-ìdáàbòbò Odù-ìdáàbòbò ni ìmọ̀-ìjìnlẹ̀ ti ìdáàbòbo ìwífún nípasẹ̀ yíyí padà sí ti aláàbò. Cryptography is the science of …
Read More

Attachment

Ìfimọ́ Ì + fi + mọ́  Fi ìfimọ́ kún un kí o tó fi ránṣẹ́. Add an attachment to it …
Read More

Submit

Fifún Verb Fi + fún (give out) Nígbà tí Ọpẹ́yẹmí kọ orúkọ sílẹ̀ tán, ó ṣíra tẹ fifun. After Ọpẹ́yẹmí …
Read More

Status

Ipò Noun Èyí ni atọ́ka sí ipò tí ẹ̀rọ tàbí ònṣàmúlò wà, fún àpẹẹrẹ; ipò ìjáde; ipò àìṣedéédé ẹ̀rọ… This …
Read More

Spoof

Ìráàyèwẹ̀rọfiṣẹ́ẹ̀jẹ́ránṣẹ́ Verb Ìrí-àyè-wọ-ẹ̀rọ-fi-iṣẹ́-ìjẹ́-ránṣẹ́ Èdè ìperí ìráàyèwẹ̀rọfiṣẹ́ẹ̀jẹ́ránṣẹ́ ni dídíbọ́n tàbí títakóró wọ inú ẹ̀rọ, inú iṣẹ́ àìrídìmú, awo àrídìmú tàbí ẹ̀rọ …
Read More

User

Òǹṣàmúlò Noun Òǹṣàmúlò ni ẹni tí ó ń ṣe àmúlò ẹ̀rọ ayárabíàṣá tàbí iṣẹ́ orí ìsopọ̀. Òǹṣàmúlò sábà máa ń …
Read More

Barometer

Òṣùwọ̀n-ọ̀rìnrìn-àyíká Noun Òṣùwọ̀n-ọ̀rìnrìn-àyíká ni ohun èlò tí a fi ń wọn ọ̀rìnrìn àyíká, tí a fi ń ṣe ìwòye ojú-ọjọ́ …
Read More

Electric meter

Òṣùwọ̀n-iná-mànàmáná Noun Òṣùwọ̀n-iná-mànàmáná ni irúfẹ́ ẹ̀rọ kan t’ó ń wọn iye iná tí ilé, iléeṣẹ́, tàbí ẹ̀rọ aloná ń lò …
Read More

Hardware

Iṣẹ́-àrídìmú Noun Pàrọ̀ Iṣẹ́-àrídìmú ẹ̀rọ-ayàwòrán. Change the camera Hardware …
Read More

Program

Iṣẹ́ Noun Iṣẹ́ Excel mi ń rá pálá. My Excel program is slow …
Read More