Buffer

Àgbájọdátà

Noun

Dátà (ìwífún alálàyé) ni ohun gbogbo tí ó ń rìn lórí ẹ̀rọ ayárabíàṣá tàbí ayélujára. Kí ohun gbogbo ó tó ṣiṣẹ́ lórí ẹ̀rọ àgbájọdátà gbọdọ̀ wáyé.

Data is every bit of information that moves on the computer or internet. Before anything works on the system it must buffer