Cellular Phone

Ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ alágbèéká Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)
Ẹ̀rọ ìbára + ẹni + sọ̀rọ̀ oní + à + gbé + ká Ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ alágbèéká, ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ alòkúta-agbára-iná, ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ ìléwọ́, tí a gé kúrú nígbà mìíràn sí ẹ̀rọ alágbèéká, ẹ̀rọ alòkúta-agbára-iná tàbí ẹ̀rọ ìbáRead More…

Crowdsourcing

Ìfèròkójọ Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)
Ìfi + èrò + kó + jọ Ìfèròkójọ jẹ́ àkójọ ìwífún, èròńgbà, tàbí iṣẹ́ láti ọwọ́ àwọn ènìyàn, tí ó jẹ́ wípé orí ẹ̀rọ ayélujára ni a ti kó o jọ. Iṣẹ́ ìfèròkójọ fi àyè gba àwọn ilé-iṣẹ́ láti dín àkókò àti owó kù bí wọ́n ṣe ń bù mu nínú omi ìmọ̀óṣe tRead More…

Open Data

Ìwífún-alálàyé Ìṣísílẹ̀ gbangba Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)
Ìwífún-alálàyé Ìṣísílẹ̀ gbangba  Ìwífún-alálàyé ìṣísílẹ̀ gbangba ni awon ìwífún-alálàyé tí ẹnikẹ́ni lè rí ààyè sí, mú lò àti pín fún elòmíràn láti tún lò. Ìjọba, okoòwò àti àwọn ènìyàn lè ṣe àmúlò àwọn ìwífún-alálàyé tí ó ṣí sílẹRead More…

Open Source Software

Iṣẹ́-àìrídìmú Olórísun Ìṣísílẹ̀-Gbangba Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)
Iṣẹ́-àìrídìmú Olórísun Ìṣísílẹ̀-Gbangbà Iṣẹ́-àìrídìmú Olórísun Ìṣísílẹ̀-Gbangba ni àkọ́kọ́ irú àjùmòlò tí a tọ́ka sí t’ó so èso rere gẹ́gẹ́ bí i ìgbésẹ̀ àjùmọ̀ṣe tí ó ti sún síwájú rékọjá ìmọ̀-ẹ̀rọ lo. Open soRead More…

Open Access

Ìráàyèsí Ìṣísílẹ̀ Gbagba wálíà Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)̀ Ara wọn ni ajàfẹ́tọ̀ọ́-ọmọ-ènìyàn tí ó ń ṣiṣẹ́ lórí àtúnpadàṣe àṣẹ-ẹ̀dá jákèjádò ilé-ayé, awon aṣòfin àkóso ìlú tí ó ń jà fún ìráàyèsí ìṣísílẹ̀-gbangba wálíà àwọn ohun ìkẹ́kọ̀ọ́ tí a fi owó ìlú ṣe àgbékalẹ̀ rẹ̀, Read More…

Automatic

Aṣiṣẹ́fúnrarẹ̀ Ẹ̀yán-ọ̀rọ̀ (Adjective)
A + ṣiṣẹ́ + fún + ara + rẹ̀ (Ohun tí ó ń ṣiṣẹ́ fúnra rẹ̀) Ìbọn tí ó ń ṣiṣẹ́ (yin ọta) fúnra rẹ̀ ni àwọn ọlọ́ṣà náà gbé wá jalè. It is an automatic gun that the robbers brought for the robbery
(the robbers brought automatic guns to rob). Read More…

Automation

Ìdàṣiṣẹ́fúnrarẹ̀ Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)
Ìdà + ṣiṣẹ́ + fún + ara + rẹ̀ 
Àdá + ṣiṣẹ́ + fún + ara + rẹ̀ Lílò irinṣẹ́ tàbí àwọn ẹ̀rọ tí ó ń dá ṣiṣẹ́ (fún ara rẹ̀) láì nílò ìkúnpá ẹ̀dá ọmọ ènìyàn.
 
Using equipment or machines that operates (automatic) on its own. Read More…