24
Sep
Off

Cellular Phone

Ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ alágbèéká

Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)

Ẹ̀rọ ìbára + ẹni + sọ̀rọ̀ oní + à + gbé + ká

  • Ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ alágbèéká, ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ alòkúta-agbára-iná, ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ ìléwọ́, tí a gé kúrú nígbà mìíràn sí ẹ̀rọ alágbèéká, ẹ̀rọ alòkúta-agbára-iná tàbí ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ sàn-án, jẹ́ ẹ̀rọ ìbáraẹnisọ̀rọ̀ tí ó ṣe é gbé kiri tí ó lè pè àti gba ìpè lórí ìsopọ̀ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ ti oǹṣàmúlò náà sì wà ní sàkàání agbára ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀.

A mobile phone, cellular phone, cell phone/cellphone, handphone/hand phone, sometimes shortened to simply mobile, cell or just phone, is a portable telephone that can make and receive calls over a radio frequency link while the user is moving within a telephone service area.

Tags: , , , , , , , , , , , , ,