8
Sep
Off

Operating System

Ètò ìṣiṣẹ́-ẹ̀rọ

Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)   

  • Ètò ìṣiṣẹ́-ẹ̀rọ ni ètò iṣẹ́-àìrídìmú tí í ṣe àkóso iṣẹ́-àìrídìmú ẹ̀rọ ayárabíàṣá, ohun-àmúlò iṣẹ́-àìrídìmú, tí ó sì ń bá àwọn onírúurú iṣẹ́ orí ẹ̀rọ ayárabíàṣá ṣiṣẹ́. … Ètò ìṣiṣẹ́-ẹ̀rọ máa ń wà ní orí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn awo tí ó ní ẹ̀rọ ayárabíàṣá nínú – láti orí ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ alòkúta-agbára-iná àti àwọn àpótí ẹ̀rọ ìṣiré títí kan àwọn apèsè ibùdó ìtakùn àti àwọn ẹ̀rọ ayárabíàṣá gbàngbà.

An operating system (OS) is system software that manages computer hardware, software resources, and provides common services for computer programs. … Operating systems are found on many devices that contain a computer – from cellular phones and video game consoles to web servers and supercomputers.

 

Tags: , , , , , , ,