Iṣẹ́-àìrídìmú Olórísun Ìṣísílẹ̀-Gbangba
Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)
Iṣẹ́-àìrídìmú Olórísun Ìṣísílẹ̀-Gbangbà
- Iṣẹ́-àìrídìmú Olórísun Ìṣísílẹ̀-Gbangba ni àkọ́kọ́ irú àjùmòlò tí a tọ́ka sí t'ó so èso rere gẹ́gẹ́ bí i ìgbésẹ̀ àjùmọ̀ṣe tí ó ti sún síwájú rékọjá ìmọ̀-ẹ̀rọ lo.
Open source software is cited as the first domain where networked open sharing produced a tangible benefit as a movement that went much further than technology.
Using equipment or machines that operates (automatic) on its own.