15
Sep
Off

Open Access

Ìráàyèsí Ìṣísílẹ̀ Gbagba wálíà

Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)̀

  • Ara wọn ni ajàfẹ́tọ̀ọ́-ọmọ-ènìyàn tí ó ń ṣiṣẹ́ lórí àtúnpadàṣe àṣẹ-ẹ̀dá jákèjádò ilé-ayé, awon aṣòfin àkóso ìlú tí ó ń jà fún ìráàyèsí ìṣísílẹ̀-gbangba wálíà àwọn ohun ìkẹ́kọ̀ọ́ tí a fi owó ìlú ṣe àgbékalẹ̀ rẹ̀, ìṣe-ìwádìí àti ìwífún-alálàyé, àti àwọn oníṣẹ́-ọpọlọ tí ó mọ rírì pínpín iṣẹ́ fún ìlò gbogboògbò.

This includes activists working on copyright reform around the globe, policymakers advancing policies mandating open access to publicly funded educational resources, research and data, and creators who share a core set of values.

Tags: , , , , , , , ,