Open Data

Ìwífún-alálàyé Ìṣísílẹ̀ gbangba

Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)

Ìwífún-alálàyé Ìṣísílẹ̀ gbangba 

  • Ìwífún-alálàyé ìṣísílẹ̀ gbangba ni awon ìwífún-alálàyé tí ẹnikẹ́ni lè rí ààyè sí, mú lò àti pín fún elòmíràn láti tún lò. Ìjọba, okoòwò àti àwọn ènìyàn lè ṣe àmúlò àwọn ìwífún-alálàyé tí ó ṣí sílẹ̀ gbangba fún ìmúwá ànfààní fún àwùjọ, ọro-ajé àti àyíká.

Open data is data that anyone can access, use and share. Governments, businesses and individuals can use open data to bring about social, economic and environmental benefits.