Ìdàṣiṣẹ́fúnrarẹ̀
Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)
Ìdà + ṣiṣẹ́ + fún + ara + rẹ̀
Àdá + ṣiṣẹ́ + fún + ara + rẹ̀
- Lílò irinṣẹ́ tàbí àwọn ẹ̀rọ tí ó ń dá ṣiṣẹ́ (fún ara rẹ̀) láì nílò ìkúnpá ẹ̀dá ọmọ ènìyàn.
Using equipment or machines that operates (automatic) on its own.