15
Mar
Off

Configuration

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ-iṣẹ́

Verb

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ-iṣẹ́

Bí a bá ń sọ nípa ẹ̀rọ-ayárabíàṣá, ìtòlẹ́sẹẹsẹ-iṣẹ́ ni bí a ṣe to ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan, àti àwọn àṣàyàn rẹ. Fún àpẹẹrẹ, ó lè jẹ́ irú iṣẹ́ àrídìmú ìṣàsopọ̀, àti bí a ṣe gbé ìṣàsopọ̀ náà kalẹ̀.

When referring to a computerconfiguration refers to how its components are arranged, and how its options are set. For instance, it can refer to what kind of hardware is connected, and how those connections are set up.

 

Tags: , , , , ,