27
Mar
Off

Mobile Data

Owóòlò-ayélujára orí ẹ̀rọ-alágbèéká

Noun

Owó + ìlò + ayélujára orí ẹ̀r-alágbèéká

  • Owóòlò-ayélujára orí ẹ̀rọ-alágbèéká ni àwọn àkópọ̀ ohun orí ayélujára tí a gbé sórí ẹ̀rọ bí i ẹ̀rọ-alágbèéká àti ẹ̀rọ-ọlọ́pọ́n tí ó la orí ìsopọ̀ àìlokùn ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́. 

Mobile data is Internet content delivered to mobile devices such as smartphones and tablets over a wireless cellular connection. 

Tags: , ,