27
Mar
Off

Spoof

Ìráàyèwẹ̀rọfiṣẹ́ẹ̀jẹ́ránṣẹ́

Verb

Ìrí-àyè-wọ-ẹ̀rọ-fi-iṣẹ́-ìjẹ́-ránṣẹ́

  • Èdè ìperí ìráàyèwẹ̀rọfiṣẹ́ẹ̀jẹ́ránṣẹ́ ni dídíbọ́n tàbí títakóró wọ inú ẹ̀rọ, inú iṣẹ́ àìrídìmú, awo àrídìmú tàbí ẹ̀rọ ayárabíàṣá lòmìíràn. 

The term spoof refers to hacking or deception that imitates another person, software program, hardware device, or computer. 

 

Tags: , , , ,