Ìsanwósí
Noun
Ìsan + owó + sí (to pay to have access to something)
- Mo ṣe ìsanwósí DSTV.
I did a DSTV subscription.
Ìfi + orúkọ + sílẹ̀ (to put down one's name/register for a purpose; for access to something)
- Jẹ́ kí a lọ ṣe ìforúkọsílẹ̀ fún owó-ìlò-ayélujára
Let us go for subscription for internet data.