16
Mar
Off

Demo

Ìfihàn ní gbangba

Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) 

Ìfihàn ní gbangba

  • Iléeṣẹ́ náà ṣe ìfihàn-ní-gbangba láti polówó ọjà rẹ̀ tuntun

The company did a demonstration to promote her new product

  • Ẹgbẹ́ akọrin tàkàsúfèé àṣẹ̀ṣẹ̀ dá ń ṣe ìfihàn ní gbangba fún ìgbáradì ìkáhùnsílẹ̀ àwo orin wọn

The newly formed hip-hop group is doing a demo in preparation for the recording of its music album

Tags: , , , , , , , ,