16
Mar
Off

Interactive Media

Àjúmọ̀ṣe Ìkànnì ìkéde

Ọ̀rọ̀ àpọ́nlé (Adjective) 

  • Àjúmọ̀ṣe Ìkànnì ìkéde ni àwọn ohunèlò orí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá tí ó máa ń f’èsì sí ohunkóhun tí ònṣàmúlò bá ṣe nípasẹ̀ ìgbéjáde àwọn àkóónú ọ̀rọ̀, àwòrán tí ó ń ṣípò, àwòrándààyè, àwòrán-olóhùn, ohùn, àti àwọn ohun ìṣeré oláwòrán-olóhùn.

Interactive media refers to products and services on digital computer-based systems which respond to the user’s actions by presenting content such as text, moving image, animation, video, audio, and video games.

 

Tags: , , , , , , , , , , , , , , ,