16
Mar
Off

Paywall

Odiìsanwó

Noun

Gbogbo ibùdó ìtakùn àgbáyé kọ́ ni ènìyàn lè mú àkóónú rẹ̀ lò ní ọ̀fẹ́, àwọn kan ń gba owó àsanlò kí òǹṣàmúlò ó tó lè rí àyè sí ohun tí wọ́n bá fẹ́. Odi ìsanwó (ògiri ìsanwó) ni ìlànà ìpààlà tí ó dúró gẹ́gẹ́ bí ìdílọ́wọ́ tí kò jẹ́ kí ènìyàn rí àyè sí ìwífún orí ibùdó-ìtakùn láì ṣe pé ènìyàn san owó tàbí àsanlò (ìsanwósílò).

Not all websites allows one to take out of its content for free use, some accepts subscription before they allow users have access to what they want. A paywall is a method of blockage that stands like a restriction that does not give one access to content on a website without one paying or subscription.

Tags: , , , , , , ,