16
Mar
Off

Slideshow

Àfihàn onísùnún

Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)

Àfihàn onísùnún (oní + ìsún)

  • Olùkọ́ wa fi àfihàn onísùnún ṣe àgbékalẹ̀ bí a ṣe ń pa aṣọ láró nípasẹ̀ lílo ìsún àwòrán mẹ́wàá.

Our instructor used slide show to make a presentation of how clothes are dyed using ten picture slides.

Tags: , , , , , , ,