16
Mar
Off

User Interface (UI)

Oríta ìbáṣepọ̀ òǹṣàmúlò

  • Oríta tí àwọn nǹkan tàbí ọmọ ènìyàn àti nǹkan (bí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá) ti máa ń pàdé ni interface. Torí ìdí èyí, oríta ìbáṣepọ̀ òǹṣàmúlò (ìyẹn UI ní Gẹ̀ẹ́sì) ni àyè tí ìbáṣepọ̀ láàárín ẹ̀dá ọmọ ènìyàn àti ẹ̀rọ ti máa ń wáyé.

The point or place where things or human and things (like computer) meet is the interface. Therefore, a user interface (UI) is the space where interactions between human and machine occur.

Tags: , , , , , ,