17
Mar
Off

Cinematograph

Ẹ̀ro àwòrán tí ń ṣípò

Ọ̀rọ̀-ìṣe (Verb)

Ẹ̀ro àwòrán tí ń ṣípò

 

Cinematography

Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)

Yíyà àwòrán tí ń ṣípò

  • Èyí ni ọnà àti ọ̀nà lílo ẹ̀rọ-ayàwòrán fi ṣe eré-oníṣe-aláwòrán. Ọlájídé kó ẹ̀kó ìmọ̀ yíyà àwòrán tí ń ṣípò.

This is the art and methods of using cameras in making a movie. Ọlájídé is studying cinematography

Cinematographer

  • Ògbóntarìgì nínú ọnà àti ọ̀nà yíyà àwòrán tí ń ṣípò.

a specialist in the art and methods of film photography.

Tags: , , , , , , , , , , ,