17
Mar
Off

Intranet

Ìṣàsopọ̀ tinú

Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)

Ìṣàsopọ̀ ti + inú

  • Èyí ni ìṣàsopọ̀ tinú tàbí ìṣàsopọ̀ ti agbègbè kan ṣoṣo tí ó wà fún àwọn ènìyàn kan ṣoṣo. Ìyẹn ìṣàsopọ̀ abẹ́lẹ̀ tí ó jẹ́ wípé àwọn ènìyàn díẹ̀ ni ó ní àyè sí ìlò rẹ̀.

This is Intra-network or local area network for just one entity. That is a private network that only a few people has access to is use.

Tags: , , , , , , , ,