Awòhunjínjìn
Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)
Awò + ohun + jínjìn
- Awo tí a fi ń sọ nǹkan tí ó wà ní ọ̀nà jínjìn réré di nílá. Ó máa ń mú kí àyẹ̀wò sí àwọn ẹ̀dá ti ọ̀run àti àwọn nǹkan mìíràn nínú Èdùmàrè rọrùn.
A device used to magnify object from far distance. It makes analysis of the celestial bodies and universe easy.
