HOME

Káàbọ̀ sí ojúlé Yobamoodua Cultural Heritage. Ní ibí ni o ó ti ṣe àwárí àwọn onírúurú ọ̀rọ̀ ní èdè Gẹ̀ẹ́sì tí a ti tú ìmọ̀ rẹ̀ sí èdè Yorùbá. Bí o bá fẹ́ kà tàbí mọ̀ nípa ọ̀rọ̀ kan nínú ìmọ̀ ẹ̀rọ, ìwọ ṣá ti fi ọ̀rọ̀ náà sílẹ̀ kí o sì tẹ ‘ṣàwárí’, tàbí kí o lọ sí ojú-ìwé ìmọ̀ ẹ̀rọ tààrà kí o ṣàwárí ọ̀rọ̀ tí o bá ń wá. Bákan náà ni fún ìmọ̀ ìjìnlẹ̀, ìṣẹ̀lẹ̀ àtẹ̀yìnwá, èdè, iṣẹ́ ọnà àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Tẹ adarí yìí kí ó gbé ọ lọ sí ojú ìwé iṣẹ́ àkànṣe àyípadà ojú-ọjọ́ ti OE4BW 2020.

Welcome to the Homepage of Yobamoodua Cultural Heritage. Here, you will search for different words in English language and the result will be presented in Yorùbá language. If you want to read or know about a word in technology, all you have to do is input the word and click ‘search’, or navigate directly to the technology page to search a word that you are searching for. The same thing applies to words in science, history, language, arts, and so on. Click on this link to navigate to the page on the OE4BW 2020 Climate Change project for Yorùbá speakers.