21
Mar
Off
Ẹ̀rọ-ayí-ayéká Noun Ẹ̀rọ-ayí-ayéká (sátáláìtì) ni ẹ̀rọ-ojúọ̀run t'ó ń yí ayé ká tí ó sì ń mú ìtàkùrọ̀sọ r'ọrùn fún wa. Ní ọwọ́ tí a wà yìí, àwọn ẹ̀rọ-ayí-ayékátí ó ń yí bírí kárí ayé yóò fẹ́rẹ̀ẹ́ tó 2218. Satellite is an object suspended in space that orbits the earth and it also make communication possible for us. Currently there are over 2218 satellites orbiting the Earth.