17 Mar Off Scanner root Ẹ̀rọ-agbẹ̀dàwòrán Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Ẹ̀rọ-agbẹ̀dàwòrán máa ń yí àwòrán padà sí ẹ̀dà àìrídìmú fún lílò lórí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá. . Scanner converts images into digital versions for use on a computer. TECHNOLOGY