Charger

Afagbárainásẹ́rọ

Noun

(A+fi+agbára+iná+sí+ẹ̀rọ)

  • Fi afagbárainásẹ́rọ mi gbéná sínú òkúta-agbanására ẹ̀rọ-ìbánisọ̀rọ̀ alágbèéká rẹ

Use my charger to charge the battery of your mobile phone