Tag: Definition
Email Forwarding
Ìránsíwájú Ímeèlì Noun Ìránsíwájú Ímeèlì ni iṣẹ́ fífi iṣẹ́-ìjẹ́ tí a gbà sínú ojúlé àpò-ìwé orí ayélujára kan ránṣẹ́ sí ojúlé àpò-ìwé orí ayélujára ẹlòmíràn tàbí àwọn ojúlé àpò-ìwé orí ayélujára mìíràn síwájú sí i. Email forwarding refers to the operation of re-sending an email message delivered to one Read More…
User
Òǹṣàmúlò Noun Òǹṣàmúlò ni ẹni tí ó ń ṣe àmúlò ẹ̀rọ ayárabíàṣá tàbí iṣẹ́ orí ìsopọ̀. Òǹṣàmúlò sábà máa ń ní ìṣàmúlò tí ẹ̀rọ máa ń dá mọ̀ gẹ́gẹ́ bí i orúkọ-òǹṣàmúlò (tàbí orúkọ òǹṣàmúlò). A user is a person who utilizes a computer or network service. A user often has a user account aRead More…
Thermometer
Òṣùwọ̀n ìgbóná Noun Òṣùwọ̀n-ìgbóná ni ohun èlò tí a fi ń yẹ ìwọ̀n òtútù àti ìgbóná nǹkan wò láti mọ bí nǹkan náà ṣe tutù tàbí gbóná sí. A thermometer is an instrument for measuring or showing temperature (how hot or cold something is). Read More…
String
Okùn Noun Nínú ìmọ̀ ẹ̀rọ-ayárabíàṣá, okùn ni ìtòlẹ́sẹẹsẹ àwọn ààmì/ọ̀rọ̀ t’ó ń ṣiṣẹ́ kan. In computer programming, a string is a sequence of characters for a certain purpose. Read More…
Barometer
Òṣùwọ̀n-ọ̀rìnrìn-àyíká Noun Òṣùwọ̀n-ọ̀rìnrìn-àyíká ni ohun èlò tí a fi ń wọn ọ̀rìnrìn àyíká, tí a fi ń ṣe ìwòye ojú-ọjọ́ àti gíga. Baros tí ó túmọ̀ sí “ìwúwo” + meter “ìwọ̀n/òṣùwọ̀n” = Ẹ̀rọ òṣùwọ̀n èéfún afẹ́fẹ́ ojú-ọjọ́. Onímọ̀ ìjìnlẹ̀ Robert Boyle ló hu ìmọ̀ èdè-ìperí Read More…
Electric meter
Òṣùwọ̀n-iná-mànàmáná Noun Òṣùwọ̀n-iná-mànàmáná ni irúfẹ́ ẹ̀rọ kan t’ó ń wọn iye iná tí ilé, iléeṣẹ́, tàbí ẹ̀rọ aloná ń lò. An electricity meter or energy meter is a device that measures the amount of electric energy consumed by a residence, business, or an electrically powered device.
Read More…
Hardware
Iṣẹ́-àrídìmú Noun Pàrọ̀ Iṣẹ́-àrídìmú ẹ̀rọ-ayàwòrán. Change the camera Hardware. Read More…
Software
Iṣẹ́-àìrídìmú Noun Fi iṣẹ́-àìrídìmú fún àwòrán yíyà sí orí ẹ̀rọ. Install graphic design Software on the system. Read More…
Program
Iṣẹ́ Noun Iṣẹ́ Excel mi ń rá pálá. My Excel program is slow.
Read More…