Òǹṣàmúlò ni ẹni tí ó ń ṣe àmúlò ẹ̀rọ ayárabíàṣá tàbí iṣẹ́ orí ìsopọ̀. Òǹṣàmúlò sábà máa ń ní ìṣàmúlò tí ẹ̀rọ máa ń dá mọ̀ gẹ́gẹ́ bí i orúkọ–òǹṣàmúlò (tàbí orúkọòǹṣàmúlò).
A user is a person who utilizes a computer or networkservice. A user often has a user account and is identified to the system by a username (or user name). Other terms for username include login name, screenname (or screen name), account name, nickname (or nick) and handle,