22
Mar
Off

Barometer

Òṣùwọ̀n-ọ̀rìnrìn-àyíká

Noun

  • Òṣùwọ̀n-ọ̀rìnrìn-àyíká ni ohun èlò tí a fi ń wọn ọ̀rìnrìn àyíká, tí a fi ń ṣe ìwòye ojú-ọjọ́ àti gíga. Baros tí ó túmọ̀ sí “ìwúwo” + meter “ìwọ̀n/òṣùwọ̀n” = Ẹ̀rọ òṣùwọ̀n èéfún afẹ́fẹ́ ojú-ọjọ́. Onímọ̀ ìjìnlẹ̀ Robert Boyle ló hu ìmọ̀ èdè-ìperí náà (1627-1691). Ọdún 1643 ni ọmọ ilẹ̀ Italy Evangelista Torricelli tó jẹ́ onímọ̀ ẹ̀dá-àrígbéwọ̀n hùmọ̀ ohun-èlò náà tí wọ́n kọ́kọ́ pè ní ihò-àpò Torricelli.

Barometer is an instrument measuring atmospheric pressure, used especially in forecasting the weather and determining altitude. From Greek baros “weight” (from suffixed form of PIE root *gwere- (1) “heavy”) + -meter. The name probably was coined (and certainly popularized) by English scientist Robert Boyle (1627-1691). The instrument was invented 1643 by Italian physicist Evangelista Torricelli and was at first known as the Torricelli tube.

Tags: , , , , , , , , ,