22
Mar
Off

Electric meter

Òṣùwọ̀n-iná-mànàmáná

Noun

  • Òṣùwọ̀n-iná-mànàmáná ni irúfẹ́ ẹ̀rọ kan t’ó ń wọn iye iná tí ilé, iléeṣẹ́, tàbí ẹ̀rọ aloná ń lò.

An electricity meter or energy meter is a device that measures the amount of electric energy consumed by a residence, business, or an electrically powered device.

 

Tags: , , , , , , , ,