Runtime environment (RTE)

Àyíká iṣẹ́

Noun

  • Àyíká iṣẹ́ ni àyíká tí ètò ìṣiṣẹ́ ẹ̀rọ pèsè fún iṣẹ́ àìrídìmú kan láti ṣe iṣẹ́ tàbí pa itú ọwọ́ rẹ̀.

A runtime environment is the execution environment provided to an application or software by the operating system.