21
Mar
Off

Save

Ìfipamọ́

Noun

Iṣẹ́ tí mo ṣe ń ṣe ìfipamọ́ sí inú àpò-àkápọ̀ àwòrán.

The work I did is saving inside the picture folder

Fi-pamọ́

Verb

  • Fipamọ́ sí inú àpò-àkápọ̀ àwòrán.

Save it in the picture folder.

  • Ṣíra tẹ àtẹ̀ìpàṣẹ fipamọ́.

Click on save button.

Tags: , , , , , , ,