Read More 21 Mar Off Shut down root Ìpa ẹ̀rọ Noun (Ìpa ẹ̀rọ) Lọ sí pátákó-gbọọrọ-iṣẹ́, wo ọwọ́ òsì, te Bẹ̀rẹ̀ kí o ṣira tẹ ìpa ẹ̀rọ. Go to the task-bar, on the left hand side, click on Start and click shut down. Pa ẹ̀rọ Verb Adéwálé pa ẹ̀rọ nígbà tí ó parí. Adéwálé shut down when he finished Adéwálé pa ẹ̀rọ ayárabíàṣá nígbà tí ó parí. Adéwálé shut down the computer when he finished TECHNOLOGY Tags: Define, Definition, In Yoruba, Language, Shut down, Shutdown, Translate, Translation, Yoruba