Ìfimọ́
Ì + fi + mọ́
- Fi ìfimọ́ kún un kí o tó fi ránṣẹ́.
Add an attachment to it before you send.
- Mo fi àwòrán ìwé-ẹ̀rí ìmọ̀-ẹ̀rọ mọ́ iṣẹ́-ìjẹ́ tí mo fi ṣọwọ́ sí iléeṣẹ́ abániwáṣẹ́.
I attached a technology proficiency certificate to the message that I sent to the employment office.