21
Jan
Off

Clipboard

Pátákó-ìdìmú

Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)

Pátákó-ìdìmú

 

  • Pátákó kékeré tí ó ní iga ìdìmú lórí, tí ó ṣe é mú ìwé (tákàdá) dání tí ó sì ń ṣe àtìlẹ́yìn fún ìkọ̀wé
A small board with a spring clip at the top, used for holding papers and providing support for writing.

 

Ìtumọ̀ Mìíràn

Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)

Pátákó-ìdìmú

  • Nínú ìmọ̀ ẹ̀rọ̀ ayárabíàṣà, pátákó-ìdìmú ni ìbi ìpamọ̀ ìgbà díẹ̀ tí ohun tí a bá gé tàbí gbẹ̀da rẹ̀ láti ara iṣẹ́ kan máa ń wà fún ìgbélẹ̀ sínú iṣẹ́ mìíràn

In computing, clipboard is a temporary storage area where material cut or copied from a file is kept for pasting into another file.

Tags: , , , , , , , , , ,