Laptop Computer
Ẹ̀rọ-ayárabíàṣá Àgbélétantẹ̀ Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)
Ẹ̀rọ a + yára + bí + àṣá À + gbé + lé + itan + tẹ̀ Pa ojú ẹ̀rọ-ayárabíàṣá àgbélétantẹ̀ yẹn dé kí o wá. Close that laptop (computer) and come. Read More…
Ẹ̀rọ-ayárabíàṣá Àgbélétantẹ̀ Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)
Ẹ̀rọ a + yára + bí + àṣá À + gbé + lé + itan + tẹ̀ Pa ojú ẹ̀rọ-ayárabíàṣá àgbélétantẹ̀ yẹn dé kí o wá. Close that laptop (computer) and come. Read More…
Ẹ̀rọ-ayárabíàṣá Àgbélẹ̀tẹ̀ Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Brian ni ó ṣe ẹ̀rọ-ayárabíàṣá àgbélẹ̀tẹ̀ tuntun tí mo ṣẹ̀ṣẹ̀ rà. Brian made the new desktop computer that I just bought. Read More…
Pátákó-ìdìmú Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)
Pátákó-ìdìmú
Pátákó kékeré tí ó ní iga ìdìmú lórí, tí ó ṣe é mú ìwé (tákàdá) dání tí ó sì ń ṣe àtìlẹ́yìn fún ìkọ̀wé A small board with a spring clip at the top, used for holding papers and providing support for writing.
Ìtumọ̀ Mìíràn
Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)
Pátákó-ìRead More…
Ipò Noun Èyí ni atọ́ka sí ipò tí ẹ̀rọ tàbí ònṣàmúlò wà, fún àpẹẹrẹ; ipò ìjáde; ipò àìṣedéédé ẹ̀rọ… This is a pointer to the state (condition) of a device or user, for example; exit status, device malfunctioning status…
Read More…
Ibi-òǹṣàmúlò Noun Ibi òǹṣàmúlò ni aṣojú tí í ṣe ìdánimọ̀ ẹni lórí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá. Mú ibi-òǹṣàmúlò Twitter rẹ ṣiṣẹ́ padà. A profile refers to the explicit digital representation of a person’s identity. Reactivate your Twitter profile. Read More…