17
Mar
Off

Laptop Computer

Ẹ̀rọ-ayárabíàṣá Àgbélétantẹ̀

Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)

Ẹ̀rọ a + yára + bí + àṣá    À + gbé + lé + itan + tẹ̀

  • Pa ojú ẹ̀rọ-ayárabíàṣá àgbélétantẹ̀ yẹn dé kí o wá.

Close that laptop (computer) and come.

Tags: , , , , , , ,