Desktop Computer

Ẹ̀rọ-ayárabíàṣá Àgbélẹ̀tẹ̀

Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)

  • Brian ni ó ṣe ẹ̀rọ-ayárabíàṣá àgbélẹ̀tẹ̀ tuntun tí mo ṣẹ̀ṣẹ̀ rà.

Brian made the new desktop computer that I just bought.