Read More 16 Mar Off Porting root Títúmọ̀ èdè iṣẹ́ àìrídìmú Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Bí a bá ń sọ nípa èdè iṣẹ́ àìrídìmú, a kò le è yọ títúmọ̀ èdè iṣẹ́ àìrídìmú tí í ṣe aàyàn ògbufọ̀ èdè iṣẹ́ àìrídìmú kan sí èdè òmíràn. When we talk about programming language, we cannot throw aside porting which is the translation of one programming (protocol) language to another. TECHNOLOGY Tags: In Yoruba, meaning of, Porting, Programming, Programming language, What is, Yoruba