16
Mar
Off
Títúmọ̀ èdè iṣẹ́ àìrídìmú Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Bí a bá ń sọ nípa èdè iṣẹ́ àìrídìmú, a kò le è yọ títúmọ̀ èdè iṣẹ́ àìrídìmú tí í ṣe aàyàn ògbufọ̀ èdè iṣẹ́ àìrídìmú kan sí èdè òmíràn. When we talk about programming language, we cannot throw aside porting which is the translation of one programming (protocol) language to another.
19
Jan
Off
Kíkèdè-iṣẹ́ àìrídìmú Noun Kíkọ-èdè-iṣẹ́ àìrímú [Kíkèdè-iṣẹ́ àìrídìmú] Adébáyọ̀ ń kọ́ nípa ìmọ̀ kíkèdè-iṣẹ́ àìrídìmú  Adébáyọ̀ is learning about programming. Kọ èdè-iṣẹ́ àìrídìmú  Write a program.    
19
Jan
Off
Akọdùàṣírí ẹ̀rọ Noun Akọ+odù+àṣírí ẹ̀rọ [Akọdùàṣírí ẹ̀rọ] Akọ+èdè+iṣẹ́ àìrímú [Akèdè iṣẹ́ àìrímú] Akọdùàṣírí ẹ̀rọ/akèdè iṣẹ́ àìrímú mẹ́jọ ló kọ odù yẹn  It is eight developers/programmers that wrote the code.