Hard Disk

Àká iṣẹ́

Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)

  • Àká iṣẹ́ ni ibi ìpamọ́ ohun gbogbo tí à ń ṣe ní orí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá.

The hard disk is the store house of all activities that we perform on the computer.