Animation

Ìṣàwòrándààyè

Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)

Ìṣọ + àwòrán + di + ààyè

  • Mo wo ìran ìsàwòrándààyè Ṣàngó kan lórí YouTube.

    I saw/watched a Ṣàngó animation on YouTube.