19
Jan
Off
Ọkọ̀ Noun Ọkọ̀ Ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ mẹ́wàá ni aṣojú wa ń gùn Our representative drives ten cars (vehicle). Ọkọ̀ òfuurufú Boeing 737 já Boeing 737 crashed. Ọkọ̀ ojú-omi ré ní Èkó Ship/boat/canoe sink in Lagos. [caption id="attachment_2291" align="aligncenter" width="300"] Ọkọ̀ ojú-omi[/caption] Ọkọ̀ akérò kan ní ìjàmbá ní orí afárá-kẹ́ta erékùṣù Èkó One commercial vehicle had an accident on the Lagos third-mainland bridge. Ọkọ̀ abẹ́-ibúomi Submarine. Ìjọba ìpínlẹ̀...