19
Jan
Off

Vehicle

Ọkọ̀

Noun

Ọkọ̀

  • Ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ mẹ́wàá ni aṣojú wa ń gùn

Our representative drives ten cars (vehicle).

  • Ọkọ̀ òfuurufú Boeing 737 já

Boeing 737 crashed.

  • Ọkọ̀ ojú-omi ré ní Èkó

Ship/boat/canoe sink in Lagos.

Ọkọ̀ ojú-omi

  • Ọkọ̀ akérò kan ní ìjàmbá ní orí afárá-kẹ́ta erékùṣù Èkó

One commercial vehicle had an accident on the Lagos third-mainland bridge.

  • Ọkọ̀ abẹ́-ibúomi

Submarine.

  • Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó fi òfin de ọkọ̀ alùpùpù ní ìpínlẹ̀ náà

The Lagos state government banned motorcycle in the state.

  • Ọkọ̀ ojú-irin/ọkọ̀-ilẹ̀ ni mo wọ̀ lọ sí Ìbàdàn

It is a train that I boarded to Ìbàdàn.

.

Tags: , , , , , , , , , , ,