Navigate

Daríkiri Ọ̀rọ̀-Ìṣe (Verb)
Da+orí+kiri [Daríkiri] Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ gboyè daríkiri/lọ kiri ètò náà bí wọ́n ṣe ń tẹ iṣẹ́ ìwádìí wọn jáde Graduate students navigate the system as they publish research.
 
Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)
Ìda+orí+kiri [Ìdaríkiri] Ìdaríkiri ọkọ̀ lójú pópó Navigation of vehicle on the highway.
 
Read More…

Vehicle

Ọkọ̀ Noun
Ọkọ̀ Ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ mẹ́wàá ni aṣojú wa ń gùn Our representative drives ten cars (vehicle). Ọkọ̀ òfuurufú Boeing 737 já Boeing 737 crashed. Ọkọ̀ ojú-omi ré ní Èkó Ship/boat/canoe sink in Lagos. Ọkọ̀ akérò kan ní ìjàmbá ní orí afárá-kẹ́ta erékùṣù Èkó One commercial vehicle Read More…