Daríkiri
Ọ̀rọ̀-Ìṣe (Verb)
Da+orí+kiri [Daríkiri]
- Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ gboyè daríkiri/lọ kiri ètò náà bí wọ́n ṣe ń tẹ iṣẹ́ ìwádìí wọn jáde
Graduate students navigate the system as they publish research.
Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)
Ìda+orí+kiri [Ìdaríkiri]
- Ìdaríkiri ọkọ̀ lójú pópó
Navigation of vehicle on the highway.
Ìtumọ̀ Mìíràn
Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)
Ìtu+ọkọ̀ [Ìtukọ̀]
- Ìtukọ̀ ojú omi
Water (river, ocean, sea) navigation.
Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun)
Atu+ọkọ̀ [Atukọ̀]
- Atukọ̀ tajú kan, ó rí àwọn ìgárá orí òkun
The navigator gazed afar, he/she sighted the pirates.