Navigate
Daríkiri Ọ̀rọ̀-Ìṣe (Verb) Da+orí+kiri [Daríkiri] Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ gboyè daríkiri/lọ kiri ètò náà bí wọ́n ṣe ń tẹ iṣẹ́ ìwádìí wọn jáde Graduate students navigate the system as they publish research. Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Ìda+orí+kiri [Ìdaríkiri] Ìdaríkiri ọkọ̀ lójú pópó Navigation of vehicle on the highway. Ìtumọ̀ Mìíràn Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Ìtu+ọkọ̀ [Ìtukọ̀] Ìtukọ̀ ojú omi Water (river, ocean, sea) navigation. Ọ̀rọ̀-orúkọ (Noun) Atu+ọkọ̀ [Atukọ̀]...