21 Mar Off Socket root Ihò-ìtẹ̀bọ̀ Noun Ti okùn afagbárainásẹ́rọ ìbánisọ̀rọ̀ bọ ihò-ìtẹ̀bọ̀ (sọ́kẹ́ẹ̀tì) Insert the phone charger into the socket Ihò-ìtẹ̀bọ̀ gbiná The socket exploded TECHNOLOGY