Data

Ìwífún-alálàyé

Noun

  • Ìwífún-alálàyé orí ẹ̀rọ ni àwọn ìwífún tí ó la orí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá kọja tí ó jẹ́ kíkó pamọ́ sí orí ẹ̀rọ.

Data is information stored and transmissible on computer.

  • Ìwífún-alálàyé-nípa ẹni

Personal Data