22
Mar
Off

Machine Learning

Kíkọ́ Ẹ̀rọ-lẹ́kọ̀ọ́

Noun

  • Kíkọ́ ẹ̀rọ-lẹ́kọ̀ọ́ l’ó mú kí ìṣèṣàtúnkọ-ẹ̀rọ àti àsọtẹ́lẹ̀ ìpilẹ̀ṣẹ̀ ọ̀rọ̀ ó ṣe é ṣe. Kíkọ́ ẹ̀rọ-lẹ́kọ̀ọ́ jẹ́ ètò òye tí-kìí-ṣe-ti-ẹ̀dá (AI) tí ó ń fi àyè gba ẹ̀rọ láti kọ́ ẹ̀kọ́ kún ẹ̀kọ́ fún ara rẹ̀ látàrí ìrírí láì ṣe wí pé allows ènìyàn fi ìmọ̀ bọ́ ọ. Pẹ̀lú àbùdá Kíkọ́ Ẹ̀rọ-lẹ́kọ̀ọ́ àwọn iṣẹ́ àìrídìmú leè ṣá ọ̀rọ̀ ìwífún alálàyé jọ fún ara wọn tí wọn yóò sì lò ó fi kọ́ ìmọ̀ ẹ̀kọ́.

Machine Learning made auto-correction and predictive text possible. Machine learning is an application of artificial intelligence (AI) that allows systems to automatically learn and improve from experience without being explicitly programmed. With Machine learning computer programs can access data and use it learn for themselves. 

Tags: , , , , , , , , , ,