Artificial Intelligence (AI)

Òye tí-kìí-ṣe-ti-ẹ̀dá (AI) Òye tí kì í ṣe ti ẹ̀dá [ọmọ ènìyàn]
Òye Tí-kìí-ṣe-ti-ẹ̀dá (AI) jẹ́ ẹ̀ka ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ ẹ̀rọ ayárabíàṣá tí ó ń ṣe ìdàgbàsókè àwọn ẹ̀rọ oní-òye, tí ó ń ronú àti ṣiṣẹ́ bí ẹ̀dá ọmọ-ènìyàn. Fún àpẹẹrẹ ìdáfọ̀mọ̀, wíwà ojútùú síṣòro, tòun ti kíkRead More…

Text to Speech

Ọ̀rọ̀ọ́-di-ohùn Noun Ọ̀rọ̀ọ́-di-ohùn ni yó ka ohun t’ó wà lójú-ẹ̀rọ l’óhùn. Ọ̀rọ̀ọ́ di ohùn ni ọgbọ́n-àmúṣe àfọ̀ tí ó ń yí gbólóhùn ọ̀rọ̀ tí a kọ sílẹ̀ di ohùn. Nítorí àwọn tí kò ríran ni a fi pèsè ohùn àfọ̀ ti ẹ̀rọ tí yó “ka” ọ̀rọ̀ sẹ́tígbọ̀ọ́ òǹṣàmúlò. It is Text-to-speRead More…

Machine Learning

Kíkọ́ Ẹ̀rọ-lẹ́kọ̀ọ́ Noun Kíkọ́ ẹ̀rọ-lẹ́kọ̀ọ́ l’ó mú kí ìṣèṣàtúnkọ-ẹ̀rọ àti àsọtẹ́lẹ̀ ìpilẹ̀ṣẹ̀ ọ̀rọ̀ ó ṣe é ṣe. Kíkọ́ ẹ̀rọ-lẹ́kọ̀ọ́ jẹ́ ètò òye tí-kìí-ṣe-ti-ẹ̀dá (AI) tí ó ń fi àyè gba ẹ̀rọ láti kọ́ ẹ̀kọ́ kún ẹ̀kọ́ fún ara rẹ̀ látàrí ìrírí lRead More…